ORÚK¬Ọ ¬ỌMỌ YORÙBÁ LÓRÍ ÌTÀKÙN AYÉLUJÁRA: ÌFỌWỌ́-ÒSÌ JÚWE ILÉ BABA ẸNI

Authors

  • Michael Adégòkè ÀKÀNDÉ Department of African Languages and Arabic Education Emmanuel Alayande University of Education, Oyo Author

DOI:

https://doi.org/10.5281/zenodo.20767163

Keywords:

Ìkọkúkọ, Ìtàkùn ayélujára, Orúkọ Yorùbá, Òwe Yorùbá

Abstract

Ohun tí a ṣe nínú iṣẹ́ yìí ni pé a ṣe akójọpọ̀ àwọn orúkọ Yorùbá lórí ìtàkùn ayélujára ‘Facebook' tí àkọsílẹ̀ wọn tako bí a ṣe ń kọ orúkọ Yorùbá sílẹ̀ a sì kọ àwọn orúkọ náà bí ó ti tọ́ àti bí ó ti yẹ. Àwọn àṣìkọ tí à ń tọ́ka sí wọ̀nyí gùn lé ìtako òfin àti ìlànà èdè Yorùbá nítorí pé gbogbo òfin tó de sílébù ló kú inú rẹ̀ bí i kí kọ́ńsónáǹtì ó parí rẹ̀ tàbí kí kọ́ńsónáǹti ó dúró ti ara wọn. Kí àwọn ọ̀dọ́ ó yí èrò wọn padà kí orúkọ náà lè jẹ́ iṣẹ́ tí wọ́n fẹ́ kó jẹ́. Ohun tí a lérò pé iṣẹ́ yìí yóò fi kún ìmọ̀ ni pé jẹ́ àníkún ìmọ̀ nípa orúkọ jíjẹ́ ní àwùjọ Yorùbá nítorí pé kíkọ orúkọ yìí ní ìkọkúkọ ti jẹ́ kí èrò àti ìdí tí wọ́n fi sọ orúkọ náà sọnù.

Downloads

Download data is not yet available.

References

Downloads

Published

2025

How to Cite

ORÚK¬Ọ ¬ỌMỌ YORÙBÁ LÓRÍ ÌTÀKÙN AYÉLUJÁRA: ÌFỌWỌ́-ÒSÌ JÚWE ILÉ BABA ẸNI. (2026). Láàńgbàsà, 24(1), 41-50. https://doi.org/10.5281/zenodo.20767163