IPA Ẹ̀KA-ÈDÈ ÈKÓ LÓRÍ ÌFỌ́NKÁ ÀTI ÌLÒ ÀWỌN WÚNRE ̣N AṢEGÍRÍMÀ KAN NÍ YORÙBÁ ÀJÙMỌ LÒ
DOI:
https://doi.org/10.5281/zenodo.20771870Abstract
Àṣamo ̣ A ṣàkíyèsí wí pé àwọn ọ̀ ̣̀do ̣̀ kan ní agbègbè Èkó máa ń ṣe pàṣípààrọ̀ ̣̀ àwọn wúnrẹ̀ ̣̀n aṣegírámà wọ̀ ̣̀nyí: tí…bí, àti mi…mo ní àwọn ìpèdè Yorùbá kan, èyí tí ó sì máa ń fa àìbétí mu àwọn ìpèdè be ̣̀ẹ̀ ̣̀. A gbìyànjú nínú iṣe ̣̀-ìwádìí yìí láti ṣe ọ̀ ̣̀fintótó oríṣiríṣi àwọn gbólóhùn tí ìfi àwọn wúnrẹ̀ ̣̀n wọ̀ ̣̀nyẹn ro ̣̀pọ̀ ̣̀ ara wọn ti máa ń wáyé. A lo ọgbo ̣̀n ìdẹtí sí àwọn tó ń ṣafọ̀ ̣̀ lédè Yorùbá Èkó ní àwọn oríṣiríṣí ibùdókọ̀ ̣̀ atí ní ọgbà Yunifásitì Èkó. A lo tío ̣̀rì Ìtúpalẹ̀ ̣̀ Àpèjúwe láti ṣe àlàyé àwọn àkójọ èdè fáyẹ̀ ̣̀wọ̀ ̣̀ tí a gbà sílẹ̀ ̣̀ ge ̣̀ge ̣̀ bí èròjà ìwádìí. Ohun tí a rí mú bọ̀ ̣̀ ni pé àwọn ìhun tí tí àti bí ti lè ṣe pàṣípààrọ̀ ̣̀ ara wọn wà, bákan náà ni ti mi àti mo. Ohun méjì ni ó je ̣̀ kàyéfì; ìkíní ni ti ìmúgbòòrò o ̣̀ fin pàṣípààrọ̀ ̣̀ tí pẹ̀ ̣̀lú bí, tí ó je ̣̀ kí a bẹ̀ ̣̀rẹ̀ ̣̀ sí ní rí ìpèdè tí kò bá òfin gírámà mu. kàyéfì kejì ni ti fífi mi dípò mo àyọrísí èyí tí ó je ̣̀ ìpèdè tí kò tọ̀ ̣̀nà. A pe àkíyèsí àwọn oníròyìn, olùkọ , akẹ kọ̣̀ọ àti àwọn sọ̀ ̣̀rọ̀ ̣̀sọ̀ ̣̀rọ̀ ̣̀ lórí rédíò, tẹlifíṣàn àti ìwé ìròyìn gbogbo láti máa kíyèsí ohun tí wọ n ń sọ láti dènà ìtànkalẹ̣̀ àyípadà òdì tí ó fẹ máa súyọ nínú àwọn ìpèdè bẹ ẹ̣̀ .Downloads
Download data is not yet available.
References
Downloads
Published
2025
Issue
Section
Articles
How to Cite
IPA Ẹ̀KA-ÈDÈ ÈKÓ LÓRÍ ÌFỌ́NKÁ ÀTI ÌLÒ ÀWỌN WÚNRE ̣N AṢEGÍRÍMÀ KAN NÍ YORÙBÁ ÀJÙMỌ LÒ . (2026). Láàńgbàsà, 23(1), 1-10. https://doi.org/10.5281/zenodo.20771870
